BÍBÉLÌ MÍMỌ́ [PẸLU ÌRÀNLỌ́WỌ́ FÚN ÀWỌN ONÍWÀÁSÙ]
Bíbélì Mímọ́ tí a ṣe pẹlu àfojúsùn láti mú kí ó rọrùn fún àwọn Oníwàásù láti gbáradì fún ìwàásù, ati fún àwọn tó fẹ́ ní ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìmọ̀ nínú Bíbélì.
Àwọn èròjà mìíràn tó wà nínú Bíbélì yìí ni:
- Ẹgbẹ̀sán [1,800] ìlàkalẹ̀ fún ìwàásù
- Ìrànlọ́wọ́ ìpalẹ̀mọ́ fún ìwàásù
- Ìfáàrà sí ìwé Bíbélì kọ̀ọ̀kan
- Ìlàkalẹ̀ àwọn àkòrí inú ìwé kọ̀ọ̀kan
- Ìtọ́kasí ẹsẹ Bíbélì ní àfibọ̀ ẹsẹ kọ̀ọ̀kan
- Ó rọrùn láti gbé ká